Deutarónómì 10:15 BMY

15 Ṣíbẹ̀ Olúwa sì tún fi ìfẹ́ rẹ̀ hàn fún àwọn baba ńlá a yín, Ó sì fẹ́ wọn Ó sì yan ẹ̀yin ọmọ wọn láti borí gbogbo orílẹ̀ èdè títí di òní.

Ka pipe ipin Deutarónómì 10

Wo Deutarónómì 10:15 ni o tọ