Deutarónómì 10:20 BMY

20 Ẹ bẹ̀rù Olúwa Ọlọ́run yín, ẹ sì máa sìn ín. Ẹ dì í mú ṣinṣin, kí ẹ sì búra ní orúkọ rẹ̀.

Ka pipe ipin Deutarónómì 10

Wo Deutarónómì 10:20 ni o tọ