Deutarónómì 10:3 BMY

3 Mo sì kan àpótí náà pẹ̀lú igi kaṣíà, mo sì gbẹ́ síléètì òkúta méjì náà jáde bí i ti ìṣáájú. Mo sì gòkè lọ pẹ̀lú síléètì méjèèjì lọ́wọ́ mí.

Ka pipe ipin Deutarónómì 10

Wo Deutarónómì 10:3 ni o tọ