Deutarónómì 10:9 BMY

9 Ìdí nìyí tí àwọn ẹ̀yà Léfì kò fi ní ìpín tàbí ogún kan láàrin àwọn arákùnrin wọn. Olúwa ni ogún wọn gẹ́gẹ́ bí Olúwa Ọlọ́run ti sọ fún un yín.)

Ka pipe ipin Deutarónómì 10

Wo Deutarónómì 10:9 ni o tọ