Deutarónómì 11:25 BMY

25 Kò sí ẹni náà tí yóò lè kò yín lójú ìjà, Olúwa Ọlọ́run yín yóò fi ẹ̀rù àti ìwárìrì i yín sórí gbogbo ilẹ̀ náà bí ó ti ṣèlérí fún un yín ní gbogbo ibi tí ẹ bá lọ.

Ka pipe ipin Deutarónómì 11

Wo Deutarónómì 11:25 ni o tọ