Deutarónómì 11:4 BMY

4 Ohun tí ó ṣe sí àwọn jagunjagun Éjíbítì, sí kẹ̀kẹ́ ogun àti ẹlẹ́sin rẹ̀: bí ó se rì wọ́n sínú òkun pupa, bí wọ́n ṣe ń lé e yín tí Olúwa fi pa wọ́n run pátapáta títí di òní olónìí yìí.

Ka pipe ipin Deutarónómì 11

Wo Deutarónómì 11:4 ni o tọ