Deutarónómì 11:9 BMY

9 Kí ẹ ba à lè pẹ́ ní orí ilẹ̀ tí Olúwa ti búra fún àwọn baba ńlá a yín, láti fún àwọn àti àwọn ọmọ wọn: ilẹ̀ tí ń ṣàn fún wàrà àti oyin.

Ka pipe ipin Deutarónómì 11

Wo Deutarónómì 11:9 ni o tọ