Deutarónómì 12:2 BMY

2 Gbogbo ibi gíga àwọn òkè ńlá, àti òkè kéékèèkéé àti lábẹ́ gbogbo igi tí ń gbilẹ̀ níbi tí àwọn orílẹ̀ èdè tí ẹ ó lé jáde, tí ń sin òrìṣà wọn ní kí ẹ mú kúrò pátapáta.

Ka pipe ipin Deutarónómì 12

Wo Deutarónómì 12:2 ni o tọ