Deutarónómì 12:25 BMY

25 Ẹ má ṣe jẹ ẹ́, kí ó báà lè dára fún ẹ̀yin àti àwọn ọmọ yín, tí ń bọ̀ lẹ́yìn in yín. Nígbà yí ní ẹ tó ń ṣe ohun tí ó tọ̀nà lójú Olúwa.

Ka pipe ipin Deutarónómì 12

Wo Deutarónómì 12:25 ni o tọ