Deutarónómì 14:24 BMY

24 Bí ibẹ̀ bá jìn tí Olúwa Ọlọ́run rẹ sì ti bùkún fún ọ, tí o kò sì le ru àwọn ìdámẹ́wàá rẹ (nítorí pé ibi tí Olúwa yóò yàn láti fi orúkọ rẹ̀ sí jìnnà jù).

Ka pipe ipin Deutarónómì 14

Wo Deutarónómì 14:24 ni o tọ