Deutarónómì 15:17 BMY

17 kí ìwọ kí ó mú ìlu kan lu etí rẹ̀ mọ́ ara ìlẹ̀kùn, yóò sì di ẹrú rẹ láéláé. Bẹ́ẹ̀ náà ni kí o ṣe sí ìránṣẹ́ ẹrúbìnrin rẹ.

Ka pipe ipin Deutarónómì 15

Wo Deutarónómì 15:17 ni o tọ