Deutarónómì 16:10 BMY

10 Nígbà náà ni kí ẹ se àjọ̀dún ọ̀ṣẹ̀ sí Olúwa Ọlọ́run yín, nípa pípèṣè ọrẹ àtinúwá, gẹ́gẹ́ bí ìbùkún tí Olúwa Ọlọ́run yín fún un yín.

Ka pipe ipin Deutarónómì 16

Wo Deutarónómì 16:10 ni o tọ