Deutarónómì 16:8 BMY

8 Ọjọ́ mẹ́fà ní kí ẹ fí jẹ àkàrà aláìwú, ní ọjọ́ kéje, ẹ pe àjọ kan fún Olúwa Ọlọ́run yín, kí ẹ má sì ṣe iṣẹ́ kankan.

Ka pipe ipin Deutarónómì 16

Wo Deutarónómì 16:8 ni o tọ