Deutarónómì 17:11 BMY

11 Ẹ ṣe bí òfin tí wọ́n kọ́ ọ yín, àti ìpinnu tí wọ́n fún un yín. Ẹ má ṣe yípadà sọ́tùn ún tàbí sósì, kúrò nínú ohun tí wọ́n sọ fún un yín.

Ka pipe ipin Deutarónómì 17

Wo Deutarónómì 17:11 ni o tọ