Deutarónómì 17:15 BMY

15 Ẹ ríi dájú pé ọba tí Olúwa Ọlọ́run yín yàn fún un yín ní ẹ yàn. Ó gbọdọ̀ jẹ́ láàrin àwọn arákùnrin yín. Ẹ má ṣe fi àjòjì jọba lórí i yín: àní ẹni tí kì í ṣe arákùnrin ní Ísírẹ́lì.

Ka pipe ipin Deutarónómì 17

Wo Deutarónómì 17:15 ni o tọ