Deutarónómì 17:6 BMY

6 Lẹnu ẹlẹ́rìí méjì tàbí mẹ́ta ni a ó pa ọkùnrin náà tí ó yẹ láti kú, ṣùgbọ́n ẹ má ṣe pànìyàn nípaṣẹ̀ ẹlẹ́rìí kan ṣoṣo.

Ka pipe ipin Deutarónómì 17

Wo Deutarónómì 17:6 ni o tọ