Deutarónómì 18:19 BMY

19 Ẹnikẹ́ni tí kò bá sì tẹ́tí sí ọ̀rọ̀ mi tí wòlíì náà yóò sọ ní orúkọ mi, èmi fúnra à mi yóò sì béèrè lọ́wọ́ ọ rẹ̀.

Ka pipe ipin Deutarónómì 18

Wo Deutarónómì 18:19 ni o tọ