Deutarónómì 18:21 BMY

21 Ṣùgbọ́n ìwọ lè wí ní ọkàn rẹ pé, “Báwo ni àwa yóò ṣe mọ ọ̀rọ̀ tí Ọlọ́run kò sọ?”

Ka pipe ipin Deutarónómì 18

Wo Deutarónómì 18:21 ni o tọ