Deutarónómì 18:9 BMY

9 Nígbà tí o bá wọ ilẹ̀ tí Olúwa Ọlọ́run rẹ yóò fi fún ọ, ìwọ kò gbọdọ̀ kọ́ láti tẹ̀lé àwọn ọ̀nà ìríra àwọn orílẹ̀ èdè náà tí ó wà níbẹ̀.

Ka pipe ipin Deutarónómì 18

Wo Deutarónómì 18:9 ni o tọ