Deutarónómì 19:1 BMY

1 Nígbà tí Olúwa Ọlọ́run rẹ bá ti pa àwọn orílẹ̀ èdè tí yóò fi ilẹ̀ wọn fún ọ run, àti nígbà tí ìwọ bá ti lé wọn jáde tí o sì dó sí àwọn ilẹ̀ àti ilé wọn gbogbo.

Ka pipe ipin Deutarónómì 19

Wo Deutarónómì 19:1 ni o tọ