Deutarónómì 19:14 BMY

14 Má ṣe pa òkúta ààlà aládúgbò rẹ dà tí aṣíwájú rẹ fi lélẹ̀ nínú ogún tí ó gbà nínú ilẹ̀ tí Olúwa Ọlọ́run rẹ fi fún ọ láti ni ní ìní.

Ka pipe ipin Deutarónómì 19

Wo Deutarónómì 19:14 ni o tọ