Deutarónómì 19:17 BMY

17 àwọn méjèèjì tí àríyànjiyàn wà láàrin wọn gbọdọ̀ dúró níwájú Olúwa níwájú àwọn àlùfáà àti àwọn adájọ́ tí ó wà ní ibi iṣẹ́ ní ìgbà náà.

Ka pipe ipin Deutarónómì 19

Wo Deutarónómì 19:17 ni o tọ