Deutarónómì 19:3 BMY

3 Ṣe àwọn ọ̀nà sí wọn àti kí o pín ilẹ̀ tí Olúwa Ọlọ́run fún ọ gẹ́gẹ́ bí ogún sí ọ̀nà mẹ́ta nítorí kí apànìyàn lè sá níbẹ̀.

Ka pipe ipin Deutarónómì 19

Wo Deutarónómì 19:3 ni o tọ