Deutarónómì 19:8 BMY

8 Tí Olúwa Ọlọ́run rẹ bá sì fẹ́ agbègbè rẹ, gẹ́gẹ́ bí ó ti ṣe ìbúra fún àwọn baba ńlá a yín, tí ó sì fún ọ ní gbogbo ilẹ̀ tí ó ti ṣe ìlérí fún wọn,

Ka pipe ipin Deutarónómì 19

Wo Deutarónómì 19:8 ni o tọ