Deutarónómì 2:10 BMY

10 Àwọn Émímù ti gbé ibẹ̀ rí: Àwọn ènìyàn tó sígbọnlẹ̀ tó sì pọ̀, wọ́n ga bí àwọn Ánákì.

Ka pipe ipin Deutarónómì 2

Wo Deutarónómì 2:10 ni o tọ