Deutarónómì 2:20 BMY

20 (A ka ilẹ̀ yìí sí ilẹ̀ àwọn Réfáímù, tí wọ́n ti gbé níbẹ̀ rí, ṣùgbọ́n àwọn ará Ámónì ń pè wọ́n ní Sámúsúmímù.

Ka pipe ipin Deutarónómì 2

Wo Deutarónómì 2:20 ni o tọ