Deutarónómì 2:31 BMY

31 Olúwa sì bá mi sọ̀rọ̀ pé, “Kíyèsí i, mo ti bẹ̀rẹ̀ sí ní fi Síhónì àti ilẹ̀ rẹ̀ lé e yín lọ́wọ́. Báyìí, ẹ máa ṣẹ́gun rẹ̀, kí ẹ sì gba ilẹ̀ rẹ̀.”

Ka pipe ipin Deutarónómì 2

Wo Deutarónómì 2:31 ni o tọ