Deutarónómì 2:36 BMY

36 Láti Áróérì, létí odò Ánónì àti láti àwọn ìlú tí ó wà lẹ́bàá odò náà títí ó fi dé Gílíádì, kò sí ìlú tí ó lágbára jù fún wa, Olúwa Ọlọ́run wa fi gbogbo wọn fún wa.

Ka pipe ipin Deutarónómì 2

Wo Deutarónómì 2:36 ni o tọ