Deutarónómì 21:14 BMY

14 Bí inú rẹ̀ kò bá sì dùn si i, jẹ́ kí ó lọ sí ibikíbi tí ó bá fẹ́. O kò gbọdọ̀ tà á tàbí lò ó bí ẹrú, lẹ́yìn ìgbà tí o ti dójú tì í.

Ka pipe ipin Deutarónómì 21

Wo Deutarónómì 21:14 ni o tọ