Deutarónómì 22:29 BMY

29 Ó ní láti san àádọ́ta fàdákà fún baba obìnrin náà, nítorí tí ó ti bà á jẹ́. Kò lè kọ̀ ọ́ sílẹ̀ níwọ̀n ìgbà tí ó sì wà láàyè.

Ka pipe ipin Deutarónómì 22

Wo Deutarónómì 22:29 ni o tọ