Deutarónómì 24:16 BMY

16 Baba kò gbọdọ̀ kú fún àwọn ọmọ wọn tàbí kí àwọn ọmọ kú fún bàbá wọ́n; olúkúlùkù ní láti kú fún ẹ̀ṣẹ̀ òun tìkára rẹ̀.

Ka pipe ipin Deutarónómì 24

Wo Deutarónómì 24:16 ni o tọ