Deutarónómì 25:14 BMY

14 Má ṣe ní oríṣìí ìwọ̀n méjì tí ó yàtọ̀ sí ara wọn ní ilé è rẹ: ọ̀kan fífẹ̀, ọ̀kan kékeré.

Ka pipe ipin Deutarónómì 25

Wo Deutarónómì 25:14 ni o tọ