Deutarónómì 25:8 BMY

8 Nígbà náà ni àwọn àgbààgbà ìlú rẹ̀ yóò pè é, wọn yóò sì bá sọ̀rọ̀. Bí ó bá sì kọ̀ jálẹ̀ tí ó bá sọ pé, “Èmi kò fẹ́ láti fẹ́ ẹ,”

Ka pipe ipin Deutarónómì 25

Wo Deutarónómì 25:8 ni o tọ