Deutarónómì 26:10 BMY

10 àti pé ní báyìí, mo mú àkọ́so ilẹ̀ tí ìwọ Olúwa ti fún mi wá.” Gbé agbọ̀n náà ṣíwájú Olúwa Ọlọ́run rẹ, kí o sì wólẹ̀ níwájú u rẹ̀.

Ka pipe ipin Deutarónómì 26

Wo Deutarónómì 26:10 ni o tọ