Deutarónómì 26:3 BMY

3 Kí o sì sọ fun àlùfáà tí ó wà ní ibi iṣẹ́ ní àsìkò náà, pé “Mo sọ ọ́ di mímọ̀ fún Olúwa Ọlọ́run rẹ pé mo ti wá sí ilẹ̀ tí Olúwa búra fún àwọn baba wa.”

Ka pipe ipin Deutarónómì 26

Wo Deutarónómì 26:3 ni o tọ