Deutarónómì 27:19 BMY

19 “Ègún ni fún ọkùnrin náà tí ó yí ìdájọ́ po fún àléjò, aláìní baba tàbí opó”Nígbà náà ni gbogbo ènìyàn wọ̀nyí yóò wí pé, “Àmín!”

Ka pipe ipin Deutarónómì 27

Wo Deutarónómì 27:19 ni o tọ