Deutarónómì 27:25 BMY

25 “Ègún ni fún ọkùnrin náà tí ó gba àbẹ̀tẹ́lẹ̀ láti pa ènìyàn láìjẹ̀bi.”Nígbà náà ni gbogbo ènìyàn wọ̀nyí yóò wí pé, “Àmín!”

Ka pipe ipin Deutarónómì 27

Wo Deutarónómì 27:25 ni o tọ