Deutarónómì 28:38 BMY

38 Ìwọ yóò gbin irúgbìn púpọ̀ ṣùgbọ́n ìwọ yóò kórè kékeré, nítorí eṣú yóò jẹ̀ ẹ́ run.

Ka pipe ipin Deutarónómì 28

Wo Deutarónómì 28:38 ni o tọ