Deutarónómì 28:7 BMY

7 Olúwa yóò gbà fún ọ pé gbogbo ọ̀ta tí ó dìde sí ọ yóò bì subú níwájú rẹ. Wọn yóò tọ̀ ọ́ wá ní ọ̀nà kan ṣùgbọ́n wọn yóò sá fún ọ ní ọ̀nà méje.

Ka pipe ipin Deutarónómì 28

Wo Deutarónómì 28:7 ni o tọ