Deutarónómì 29:27 BMY

27 Nígbà náà ni ìbínú Olúwa ru sí ilẹ̀ wọn, débi pé ó mú gbogbo ègún tí a kọ sínú ìwé yìí wá sórí i rẹ̀.

Ka pipe ipin Deutarónómì 29

Wo Deutarónómì 29:27 ni o tọ