Deutarónómì 29:6 BMY

6 O kò jẹ oúnjẹ tàbí mu wáìnì kankan tàbí rú ohun mímu mìíràn. Mo ṣe èyí kí o lè mọ̀ pé èmi ni Olúwa Ọlọ́run rẹ.

Ka pipe ipin Deutarónómì 29

Wo Deutarónómì 29:6 ni o tọ