Deutarónómì 3:10 BMY

10 Gbogbo àwọn ìlú tí o wà ní orí òkè olórí títẹ́ náà ni a gbà àti gbogbo Gílíádì, àti gbogbo Báṣánì, títí dé Ṣálékà, àti Édíréì, ìlú àwọn ọba Ógù ní ilẹ̀ Báṣánì.

Ka pipe ipin Deutarónómì 3

Wo Deutarónómì 3:10 ni o tọ