Deutarónómì 3:13 BMY

13 Gbogbo ìyókù Gílíádì àti gbogbo Básánì, ní ilẹ̀ ọba Ógù ni mo fún ìdajì ẹ̀yà Mánásè. (Gbogbo agbégbé Ágóbù ni Básánì tí a mọ̀ sí ilẹ̀ àwọn ará Ráfátì.

Ka pipe ipin Deutarónómì 3

Wo Deutarónómì 3:13 ni o tọ