Deutarónómì 3:24 BMY

24 “Ọlọ́run Alágbára, ìwọ tí ń fi títóbi rẹ àti ọwọ́ agbára rẹ han ìránṣẹ́ rẹ. Ọlọ́run wo ló tó bẹ́ẹ̀ láyé àti lọ́run tí ó lè ṣe àwọn iṣẹ́ agbára ńlá tí o ti ṣe?

Ka pipe ipin Deutarónómì 3

Wo Deutarónómì 3:24 ni o tọ