Deutarónómì 3:28 BMY

28 Ṣùgbọ́n yan Jósúà, kí o sì gbà á níyànjú, mú un lọ́kàn le, torí pé òun ni yóò ṣíwájú àwọn ènìyàn wọ̀nyí kọjá, yóò sì jẹ́ kí wọn jogún ilẹ̀ náà tí ìwọ yóò rí.”

Ka pipe ipin Deutarónómì 3

Wo Deutarónómì 3:28 ni o tọ