Deutarónómì 30:6 BMY

6 Olúwa Ọlọ́run rẹ yóò kọ ọkàn rẹ ní ilà àti ọkàn àwọn ọmọ yín, nítorí kí o lè fẹ ẹ pẹ̀lú gbogbo àyà rẹ pẹ̀lú gbogbo ọkàn rẹ, àti ayé rẹ.

Ka pipe ipin Deutarónómì 30

Wo Deutarónómì 30:6 ni o tọ