Deutarónómì 31:11 BMY

11 Nígbà tí gbogbo Ísírẹ́lì bá wá láti fi ara hàn níwájú Olúwa Ọlọ́run wa ní ibi tí yóò yàn, ìwọ yóò ka òfin yìí níwájú wọn sí etí ìgbọ́ wọn.

Ka pipe ipin Deutarónómì 31

Wo Deutarónómì 31:11 ni o tọ