Deutarónómì 31:16 BMY

16 Olúwa sì sọ fún Móṣè pé: “Ìwọ ń lọ sinmi pẹ̀lú àwọn baba à rẹ, àwọn wọ̀nyí yóò sì ṣàgbèrè ara wọn sí ọlọ́run àjèjì ilẹ̀ tí wọn ń wọ̀ lọ láìpẹ́. Wọn yóò kọ̀ mí sílẹ̀ wọn yóò sì da májẹ̀mú tí mo bá wọn dá.

Ka pipe ipin Deutarónómì 31

Wo Deutarónómì 31:16 ni o tọ