18 Èmi yóò sì pa ojú mi mọ́ dájúdájú ní ọjọ́ náà nítorí i gbogbo ìwà búburú wọn ní yíyípadà sí ọlọ́run mìíràn.
Ka pipe ipin Deutarónómì 31
Wo Deutarónómì 31:18 ni o tọ