Deutarónómì 31:26 BMY

26 “Gba ìwé òfin yìí kí o sì fi sí ẹ̀gbẹ́ àpótí i májẹ̀mú Olúwa Ọlọ́run rẹ. Níbẹ̀ ni yóò wà bí ẹ̀rí sí ọ.

Ka pipe ipin Deutarónómì 31

Wo Deutarónómì 31:26 ni o tọ